Àwọn Adájọ́ 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọkunrin marun-un náà pada dé ọ̀dọ̀ àwọn eniyan wọn ní Sora ati Eṣitaolu, àwọn eniyan wọn bi wọ́n léèrè pé, “Báwo ni ọ̀hún ti rí?”

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:4-11