Àwọn Adájọ́ 18:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá yà sibẹ, wọ́n sì lọ sí ilé ọdọmọkunrin ọmọ Lefi, tí ó wà ní ilé Mika, wọ́n bèèrè alaafia rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:10-22