Àwọn Adájọ́ 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lọ pàgọ́ sí Kiriati Jearimu ní Juda. Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Mahanedani títí di òní olónìí; ó wà ní apá ìwọ̀ oòrùn Kiriati Jearimu.

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:4-19