Àwọn Adájọ́ 18:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ bá lọ, ẹ óo dé ibìkan tí àwọn eniyan ń gbé láìbẹ̀rù, ilẹ̀ náà tẹ́jú. Dájúdájú Ọlọrun ti fi lé yín lọ́wọ́, kò sí ohun tí eniyan ń fẹ́ ní ayé yìí tí kò sí níbẹ̀.”

Àwọn Adájọ́ 18

Àwọn Adájọ́ 18:1-14