Àwọn Adájọ́ 17:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Mika bá dáhùn pé, “Mo mọ̀ nisinsinyii pé OLUWA yóo bukun mi, nítorí pé, ọmọ Lefi gan-an ni mo gbà gẹ́gẹ́ bí alufaa.”

Àwọn Adájọ́ 17

Àwọn Adájọ́ 17:12-13