Àwọn Adájọ́ 16:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Samsoni bá bẹ ọdọmọkunrin tí ó mú un lọ́wọ́, ó ní, “Jẹ́ kí n fi ọwọ́ kan àwọn òpó tí gbogbo ilé yìí gbé ara lé kí n lè fara tì wọ́n.”

Àwọn Adájọ́ 16

Àwọn Adájọ́ 16:20-31