Àwọn Adájọ́ 16:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Filistini bá kì í mọ́lẹ̀, wọ́n yọ ojú rẹ̀, wọ́n mú un wá sí ìlú Gasa, wọ́n sì fi ẹ̀wọ̀n idẹ dè é. Wọ́n ní kí ó máa lọ àgbàdo ninu ilé ẹ̀wọ̀n.

Àwọn Adájọ́ 16

Àwọn Adájọ́ 16:14-29