Àwọn Adájọ́ 15:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Samsoni bá sọ fún wọn pé, “Bí ó bá jẹ́ pé bí ẹ óo ti ṣe nìyí n óo gbẹ̀san lára yín, lẹ́yìn náà, n óo fi yín sílẹ̀.”

Àwọn Adájọ́ 15

Àwọn Adájọ́ 15:1-8