Àwọn Adájọ́ 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Samsoni bá lọ, ó mú ọọdunrun (300) kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ láàyè, ó wá ìtùfù, ó sì so àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ náà ní ìrù pọ̀ ní meji meji, ó fi ìtùfù sí ààrin ìrù wọn.

Àwọn Adájọ́ 15

Àwọn Adájọ́ 15:1-7