Àwọn Adájọ́ 14:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Samsoni bá baba ati ìyá rẹ̀ lọ sí Timna ní ọjọ́ kan. Bí ó ti dé ibi ọgbà àjàrà àwọn ará Timna kan báyìí, ni ọ̀dọ́ kinniun kan bá bú mọ́ ọn.

Àwọn Adájọ́ 14

Àwọn Adájọ́ 14:2-9