Àwọn Adájọ́ 14:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan náà rí i, wọ́n mú ọgbọ̀n ninu àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ wá láti wà pẹlu rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 14

Àwọn Adájọ́ 14:1-20