Àwọn Adájọ́ 13:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ṣọ́ra, o kò gbọdọ̀ mu ọtí waini tabi ọtí líle, bẹ́ẹ̀ ni o kò gbọdọ̀ jẹ ohunkohun tí ó jẹ́ aláìmọ́.

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:1-6