Àwọn Adájọ́ 13:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Manoa bá mú ọmọ ewúrẹ́ náà, pẹlu ẹbọ ohun jíjẹ, ó fi wọ́n rúbọ lórí òkúta kan sí OLUWA tí ń ṣe iṣẹ́ ìyanu.

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:14-21