Àwọn Adájọ́ 13:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Manoa bá bèèrè lọ́wọ́ angẹli OLUWA náà, ó ní, “Kí ni orúkọ rẹ kí á lè dá ọ lọ́lá nígbà tí ọ̀rọ̀ rẹ bá ṣẹ.”

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:11-22