Àwọn Adájọ́ 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò gbọdọ̀ fẹnu kan ohunkohun tí ó bá jáde láti inú èso àjàrà, kò gbọdọ̀ mu waini tabi ọtí líle tabi kí ó jẹ ohunkohun tí ó jẹ́ aláìmọ́. Gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún un ni kí ó ṣe.”

Àwọn Adájọ́ 13

Àwọn Adájọ́ 13:13-17