Àwọn Adájọ́ 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹfuta ṣe aṣiwaju ní ilẹ̀ Israẹli fún ọdún mẹfa. Nígbà tí ó ṣaláìsí, wọ́n sin ín sí Gileadi, ìlú rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 12

Àwọn Adájọ́ 12:3-13