Àwọn Adájọ́ 12:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹfuta bá dá wọn lóhùn, ó ní, “Nígbà kan tí ogun bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ará Amoni ati èmi pẹlu àwọn eniyan mi, tí mo ranṣẹ pè yín, ẹ kò gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ wọn.

Àwọn Adájọ́ 12

Àwọn Adájọ́ 12:1-12