Àwọn Adájọ́ 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹfuta bá sá jáde kúrò lọ́dọ̀ àwọn arakunrin rẹ̀, ó ń gbé ilẹ̀ Tobu. Àwọn aláìníláárí ati àwọn oníjàgídíjàgan kan bá kó ara wọn jọ sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n bá ń bá a digun jalè káàkiri.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:1-7