Àwọn Adájọ́ 11:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí OLUWA bá bà lé Jẹfuta, ó bá kọjá láàrin Gileadi ati Manase, ó lọ sí Misipa ní ilẹ̀ Gileadi, láti ibẹ̀ ni ó ti lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Amoni.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:26-34