Àwọn Adájọ́ 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí wọn ń bọ̀ láti ilẹ̀ Ijipti, ààrin aṣálẹ̀ ni wọ́n gbà títí wọ́n fi dé Òkun Pupa, tí wọ́n sì fi dé Kadeṣi.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:11-21