Àwọn Adájọ́ 11:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹfuta ará Gileadi jẹ́ akikanju jagunjagun, ṣugbọn ọmọ aṣẹ́wó ni; Gileadi ni baba rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 11

Àwọn Adájọ́ 11:1-5