Àwọn Adájọ́ 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Jairi ará Gileadi ni ó di adájọ́ lẹ́yìn rẹ̀, ó jẹ́ aṣiwaju ní ilẹ̀ Israẹli fún ọdún mejilelogun.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:1-6