Àwọn Adájọ́ 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Sidoni, àwọn ará Amaleki, ati àwọn ará Maoni ń pọn yín lójú; ẹ kígbe pè mí, mo sì gbà yín lọ́wọ́ wọn.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:10-18