Àwọn Adájọ́ 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Juda gbógun ti ìlú Jerusalẹmu; wọ́n gbà á, wọ́n fi idà pa gbogbo àwọn tí wọn ń gbébẹ̀, wọ́n sì sun ún níná.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:1-16