Àwọn Adájọ́ 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Adonibeseki sá, ṣugbọn wọ́n lé e mú. Wọ́n gé àtàǹpàkò ọwọ́ ati ti ẹsẹ̀ rẹ̀ mejeeji.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:1-7