Àwọn Adájọ́ 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Juda gbéra, wọ́n lọ gbógun ti àwọn ará Kenaani ati àwọn ará Perisi. OLUWA fi wọ́n lé àwọn ọmọ Juda lọ́wọ́, wọ́n sì ṣẹgun ẹgbaarun (10,000) ninu wọn ní Beseki.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:2-11