Àwọn Adájọ́ 1:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Amori ń lé àwọn ọmọ Dani sẹ́yìn sí àwọn agbègbè olókè, nítorí pé wọn kò fẹ́ gba àwọn ọmọ Dani láàyè rárá láti sọ̀kalẹ̀ sí pẹ̀tẹ́lẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:26-36