Àwọn Adájọ́ 1:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli di alágbára sí i, wọ́n ń fi tipátipá kó àwọn ará Kenaani ṣiṣẹ́, ṣugbọn wọn kò lé wọn kúrò láàrin wọn patapata.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:26-33