Àwọn Adájọ́ 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ Bẹnjamini kò lé àwọn ará Jebusi tí wọn ń gbé Jerusalẹmu jáde; láti ìgbà náà ni àwọn ará Jebusi ti ń bá àwọn ọmọ Bẹnjamini gbé ní Jerusalẹmu títí di òní olónìí.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:17-25