Àwọn Adájọ́ 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yà Juda ni kí ó kọ́ dojú kọ wọ́n, nítorí pé, mo ti fi ilẹ̀ náà lé wọn lọ́wọ́.”

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:1-11