Àwọn Adájọ́ 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Otinieli, ọmọ Kenasi, àbúrò Kalebu, ṣẹgun ìlú náà, Kalebu bá fi Akisa, ọmọbinrin rẹ̀ fún un kí ó fi ṣe aya.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:3-21