Amosi 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA tí ó kọ́ ilé gíga rẹ̀ sí ojú ọ̀run,tí ó gbé awọsanma lé orí ilẹ̀ ayétí ó pe omi òkun jáde,tí ó sì dà á sórí ilẹ̀,OLUWA ni orúkọ rẹ̀.

Amosi 9

Amosi 9:1-15