Amosi 9:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní ọjọ́ náà, n óo gbé àgọ́ Dafidi tí ó ti wó ró. N óo tún odi rẹ̀ mọ, n óo tún un kọ́ yóo sì rí bí ó ti wà tẹ́lẹ̀ rí.

Amosi 9

Amosi 9:6-15