Amosi 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ti fi ògo Jakọbu búra; ó ní, “Dájúdájú n kò ní gbàgbé ẹyọ kan ninu iṣẹ́ ọwọ́ yín.

Amosi 8

Amosi 8:1-13