Amosi 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́ èyí, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń rẹ́ àwọn aláìní jẹ, tí ẹ múra láti pa àwọn talaka run lórí ilẹ̀ patapata.

Amosi 8

Amosi 8:2-13