Amosi 6:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò fẹ́ gbà pé ọjọ́ ibi ti súnmọ́ tòsí; ṣugbọn ẹ̀ ń ṣe nǹkan tí yóo mú kí ọjọ́ ẹ̀rù tètè dé.

Amosi 6

Amosi 6:1-12