Amosi 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA sọ nípa yín, gbogbo ẹ̀yin tí a kó jáde láti ilẹ̀ Ijipti: OLUWA ní,

Amosi 3

Amosi 3:1-7