Amosi 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà, àárẹ̀ yóo mú àwọn tí wọ́n lè sáré; ipá àwọn alágbára yóo pin, akikanju kò sì ní lè gba ara rẹ̀ sílẹ̀.

Amosi 2

Amosi 2:9-16