Amosi 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi fúnra mi ni mo mu yín jáde wá láti ilẹ̀ Ijipti, mo mu yín la aṣálẹ̀ fún ogoji ọdún, kí ẹ lè gba ilẹ̀ àwọn ará Amori.

Amosi 2

Amosi 2:1-12