Amosi 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, n óo sọ iná sí ààfin Hasaeli, yóo sì jó ibi ààbò Benhadadi kanlẹ̀.

Amosi 1

Amosi 1:1-11