Amosi 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Amosi ní:“OLUWA bú ramúramù lórí Òkè Sioni,ó fọhùn ní Jerusalẹmu;àwọn pápá tútù rọ,ewéko tútù orí òkè Kamẹli sì rẹ̀.”

Amosi 1

Amosi 1:1-3