Àwọn tí ń rìn ninu òkùnkùn ti rí ìmọ́lẹ̀ ńlá.Ìmọ́lẹ̀ sì ti tàn sí àwọn tí ń gbé ninu òkùnkùn biribiri.