Aisaya 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kí ọmọ náà tó mọ bí a tí ń pe ‘Baba mi’ tabi ‘Mama mi’, wọn óo ti kó àwọn nǹkan alumọni Damasku ati ìkógun Samaria lọ sí Asiria.

Aisaya 8

Aisaya 8:2-5