Aisaya 7:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí Samaria ni olú-ìlú Efuraimu, Ọmọ Remalaya sì ni olórí Samaria. Bí ẹ kò bá gbàgbọ́ ẹ kò ní fẹsẹ̀ múlẹ̀.”

Aisaya 7

Aisaya 7:1-19