Aisaya 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní ọjọ́ náà OLUWA yóo súfèé pe àwọn eṣinṣin tí ó wà ní orísun gbogbo odò Ijipti ati àwọn oyin tí ó wà ní ilẹ̀ Asiria.

Aisaya 7

Aisaya 7:13-25