Aisaya 66:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́ ariwo ninu ìlú,ẹ gbọ́ ohùn kan láti inú Tẹmpili,ohùn OLUWA ni,ó ń san ẹ̀san fún àwọn ọ̀tá rẹ̀.

Aisaya 66

Aisaya 66:1-14