Aisaya 65:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò ní ṣe iṣẹ́ àṣedànù,wọn kò ní bímọ fún jamba;nítorí ọmọ ẹni tí OLUWA bukun ni wọn yóo jẹ́,àwọn ati àwọn ọmọ wọn.

Aisaya 65

Aisaya 65:14-25