Aisaya 64:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ti dáná sun ilé mímọ́ wa tí ó lẹ́wà,níbi tí àwọn baba wa ti yìn ọ́,gbogbo ibi dáradára tí a ní, ló ti di ahoro.

Aisaya 64

Aisaya 64:1-12