Aisaya 62:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn orílẹ̀-èdè yóo rí ìdáláre rẹ,gbogbo ọba ni yóo rí ògo rẹ;orúkọ tuntun, tí OLUWA fúnra rẹ̀ yóo sọ ọ́,ni a óo máa pè ọ́.

Aisaya 62

Aisaya 62:1-10