Aisaya 61:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo tún àlàpà ahoro àtijọ́ kọ́,wọn óo tún gbogbo ilé tí ó ti wó lulẹ̀ kọ́,wọn óo sì tún ìlú tí a ti parun láti ọdún gbọọrọ kọ́.

Aisaya 61

Aisaya 61:1-7